You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Mo ké bòòsí tòò bí mo ṣe bí ìbejì, ti ọ̀kan jẹ́ àfín, ìkejì jẹ́ dúdú-Màmá Ọlátẹ́jú
Ọ̀pọ́ to mọ wi pe Taiwo ati Kehinde Olateju jẹ ibeji ni o maa n wo wọn ni awoyanu.
Awọn ibeji ti ọkan ninu wọn jẹ afin ko wọpọ nilu. Ṣugbọn lati ọjọ ti wọn ti bi wọn, iya wọn ni ayọ nikan ni wọn n mu ba oun.