You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Nollywood: Bẹbẹ ń lọ ní ibùdó yíya sinimá Àgbésọrísùn
Sinima ṣiṣe lorilẹede NAijiria ti di itẹwọgba lagbaye, ṣugbọn bawo ni awọn sinima yii ṣe n parapọ di ohun ti araye n tẹwọgba?
idahun si ibeeere yii lo sun ikọ BBC News Yoruba lọ si ibudo iya sinima kan ti akọle rẹ n jẹ Àgbésọrísùn.
Yọmi Fabiyi lo kọ ere naa, Abbey Lanre lo si dari rẹ.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Ìyàwó mi gbà kí n kó ipa ìfẹnukonu tó wọra - Yemi Blaq
- Ọmọ Ibadan yin iṣẹ́ Woli Arole
- Níbo làwọn òṣèré apanilẹ́rìn ín wọ̀nyí tó pilẹ̀ sínima àgbéléwò Yorùbá wà?
- Omotola Jalade ní Nàìjíríà dàbí ọ̀run àpáàdì lábẹ́ ìjọba Buhari
- Ọmọogun ilẹ̀ Amẹ́ríkà ni mí tẹ́lẹ̀ kí n tó di aláwàdà - Oluwakaponeski
- Duro Ladipọ, ìlúmọ̀ọ́ká òṣèré tíátà àti ọmọ àlúfà tí kò gbàgbé àṣà ìbílẹ̀
- Ọ̀pọ̀ òṣèré tíátà tó ń sàìsàn ni kò ṣe dáadáa f'ẹ́gbẹ́ - Jide Kosọkọ
- Deji àti Charly Boy tako ara wọn lórí fọ́nrán tó jáde
- Ìyá àgbà Ọlayinka, arúgbó tó ń ṣoge bí omidan