Àwọn àwòrán tó làmìlaaka níbi ayẹyẹ àpéjẹ ìdúpẹ́ Aisha Buhari

Àwọn ènìyàn jàǹkàǹjàǹkàǹ ló pé jú síbi ayẹyẹ àpéjẹ ìdúpẹ́ Aisha Buhari tó wáyé nílé ìjọba l'Abuja.