Yomi Fabiyi: Lẹ́yìn tí èmi àti ìyàwó mi pínyà, mó ti gbé ǹkan ire ṣe

Òṣèré tíátà Yorùbá Yomi Fabiyi sọ̀rọ̀ lórí bí ìgbéyàwó rẹ̀ pẹ̀lú ìyàwó tó fẹ́ lókè òkun ṣe yí dà sí bí kò ṣe rò ó nítorí àyípadà àdéhùn.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ sí: