Ọrẹ Falọmọ: Buhari yóò rí ìbò Yorùbá gbà ju Atiku, Ọbasanjọ lọ

Agba ọjẹ kan ni ilẹ Yoruba, to tun jẹ dokita fun M.K.O Abiola nigba aye rẹ, Dokita Ọre Falomo ti sọ pe, ko tọ si Oloye Olusẹgun Ọbasanjo lati sọ ẹni ti Yoruba yoo dibo yan ni ọdun 2019, gẹgẹbi aarẹ.

Falomo sọ eyi lasiko to n ba BBC Yoruba sọrọ lori ajumọse Ọbasanjo ati Atiku, ti awọn kan sọ pe wọn ko gba tara wọn lasiko isejọba Ọbasanjo.

Falomo fikun wi pe, awọn ọmọ Yoruba yoo dibo fun Aarẹ Muhammadu Buhari ju ẹnikẹni lọ, ni idibo gbogbo-ogbo ọdun 2019.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: