You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Lanko Adeọla Ṣorẹmi: Ọlọrun nìkan ló ń bá wa to ilé wa
Adeọla Ṣorẹmi ti gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Princess Lanko ti bu ẹnu àtẹ́ lu kí àwọn òṣèré má máa ráyé fún ẹbí wọn léyìí tó ni òun náà jẹ́ ọ̀kan.