You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Òṣìṣẹ́ fẹyinti sunkun sí Aregbesola lọrùn lọsun
Ìgboro ìlú Oshogbo kún fọfọ pẹlú bí awọn oṣiṣẹ feyinti ni ìpínlẹ̀ Osun ti ṣe wọde láti fí ehonu hàn sí bí wọn ti ṣe ní Gómìnà Aregbesola kò sàn owó oṣu awọn.
Oṣù diẹ loku ti Aregbesola yóò ló lórí aleefa gẹgẹ bí Gómìnà.