You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Osun election: Àwòrán ìbò abẹ́nú APC, PDP àti Accord
Ìpínlẹ̀ Osun gbà alejo lópin ọsẹ nígbà tí ẹgbẹ òṣèlú mẹta otooto dibo yan oludije ti yóò sójú wọn nínú ìdìbò Gómìnà Osun.