You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Hajj 2018: Àwòrán bí àwọn Alálàájì àkọ́kọ́ ṣe ń gbéra l’Abuja
Àwọn alálàájì láti ìpínlè Kogi ni wọ́n ṣíde ìrìnàjò Hajj 2018 ní orílè-èdè Nàìjíríà.