Ọmọge Campus: Àwọn ọmọ, ẹbi, ara ati ọrẹ ló sìnkú Aisha

Òseré náà jáde laàyé ní ọjọ́ Ọjọ́rú nitorí àìsàn jẹjẹrẹ ọyàn ni ile rẹ̀ ní Canada.