You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
World Food Day 2020, Yollywood; Dayọ̀ Amúsà jẹ́wọ́ ara rẹ̀ lórí ètò Àjẹpọ́nulá
Gbajúgbajà òsèré tíátà Yoruba, Dayọ̀ Amúsà kò kàn jẹ́ obìnrin òsèré lásán, ó tún jẹ́ obìnrin nínú ilé.
Ṣé ẹyin mọ awọn eroja ẹlẹmi meje to n sọ ila alasepọ di ajẹpọnnula?
Dayọ Amusa ṣe bẹbẹ lati se ila alasepọ ni eyi to n da ọpọ eeyan lọfun tolo nibi.
Loni ayajọ ọjọ ounjẹ ni gbogbo agbaye, BBC sọ anfani jijẹ awọn ounjẹ aṣaraloore ati ipa awọn eroja isebẹ bii ti ninu ila alasepọ yii ti Dayo Amusa se fun wa.
- Pásítọ̀ Enoch Adeboye darapọ̀ mọ̀ #ENDSARS, ó fún ìjọba Nàìjíríà ní ìmọ̀ràn ọ̀nà àbáyọ
- Wo àwọn ojúṣe àti èèwọ̀ fún ikọ̀ ọlọ́pàá SWAT tó gba iṣẹ́ lọ́wọ́ SARS
- Mọ̀ nípa iPhone 12, fóònù ológo 5G tí kìí lo "Charger” tó ṣẹ̀ṣẹ̀ jáde
- Mi ò mọ̀ nípa àwọn tọ́ọ̀gì tó da ìwọ́de EndSARS Alausa rú, mo ṣì wà lẹ́yìn yín digbí! - Sanwoolu
- Àṣé àṣírí wà nínú Hijabu tí Aisha Yesufu ń wọ̀ lọ ìwọ́de