You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ fásitì Adekunle Ajasin, Akungba-Akoko fẹ̀hónú hàn ní ìpínlẹ̀ Èkó
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ fásitì Adekunle Ajasin, Akungba-Akoko tú síta kẹ̀tí-kẹ̀tí lónì''i láti fẹ̀hónú hàn lórí i àfikún owó iléèwé tí ìjọba ìpínlẹ̀ Òndò paláṣẹ.