DJ Spinall: Orin tí kò ní ìtumọ̀ ni ayé ń tẹ́wọ́gbà

Olórin tàkansúfèé DJ Spinall ní Orin tí kò ní ìtumọ̀ ni ayé ń tẹ́wọ́gbà, tí wọn yóò sì máa gbókìtì.

Ó ní kìí se gbogbo orin ló yẹ kó ní ìtumọ̀ nítorí ọ̀pọ̀ èèyàn kìí tẹ́wọ́gbà orin tó ní ìtumọ̀ lọ́pọ̀ ìgbà.

Ó fi kún un pé ayé àtijọ́ ti yàtọ̀ sí òde òní

DJ Spinall ní òun ní ìfẹ́ láti máa gbé àsà Yorùbá lárugẹ.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: