You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Yomi Lanso wipe ka jọ gbadun laye
Yomi Fash Lanso wipe oun tako ki awọn ojisẹ Olorun maa fẹla laye sugbọn ki wọn ma sọ fun ọmọ ijo pe igbadun tiwọn wa lọrun.