You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Alaafin Adeyemi: Ọmọ aláàfin sọ̀rọ̀ lórí àṣírí agbára bàbá rẹ̀ bí Kábíyèsí ṣe bí ìbejì ní ẹ̀ẹ̀mẹta láàrin oṣù mẹ́jọ
Aláàfin ìlú Ọyọ, Ọba Lamidi Ọlayiwọla Adeyẹmi Kẹta tún ti bí ìbejì mi i.
Ìgbà kẹta nìyíì ti yóò bí ìbejì l'ọ́dún 2018 nìkan ṣoṣo.
Bákan nàá ló ti bí ìbẹta rí.
Ọ̀kan lára àwọn olorì rẹ̀, Anuoluwapọ Adeyẹmi ló tún bí ìbejì ọkùnrin kan àti obìnrin láìpẹ́ yìí, èyí tó sọ ọ́ di ìkẹta láàrin oṣù mẹ́jọ.
- Báwo ni ìlù gángan se bẹ̀rẹ̀ ?
- Oluwo sọ f'Aláàfin pé k'Olorì máa dádé
- Aarẹ ọna kakanfo Yoruba
- Alaafin ìlú Oyo gba adé lórí babalawo tó pe ara rẹ lọ́ba, ó fi adé náà kọ́ igi
- Kìí ṣe oògùn ìbílẹ̀ ni mo fi ń rántí déètì ọjọ́ àti oṣù lórí, ohun tí mo ṣe nígbà èwe rèé - Alaafin Oyo
- Ọba Lamidi Adeyẹmi, òṣìṣẹ́ adójútòfò àti Abẹ̀ṣẹ́kùbíòjò kó tó jọba
Àwọn olorì méjì kan ti bi ìbejì l'ọ́dún 2018.
Àwọn Ayaba naa ni Olori Badirat Ọlaitan Adeyẹmi tó bí ìbejì ọkùnrin nínú oṣù Kẹta.
Bákan nàá ni Olorì Memunat Omowumi Adeyẹmi tóbákan nàá.
Njẹ ki wa ni asiri agbara Alaafin, ẹni to ti le ni ọgọrin ọdun, to fi nbi ibeji ati ibẹta ni ọpọ igba?
Èyí ni ìbéèrè tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọmọ Yorùbá n bèérè.
Ọmọọbabinrin Alaafin, Olubunmi Labiyi bá BBC Yoruba sọ̀rọ̀ nínú fọ́nrán tó wà l'ókè.