You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
King Charles Coronation: Èrò àwọn ọmọ Adulawo yàtọ̀ lórí ìgbadé Oba Charles !!!
Ojọ kẹfa, oṣu kẹfa, ọdun 2023 ni ayẹyẹ iwuye Oba charles kẹta yóò wáyé nilu Oba.
Kini ipa ti ẹ ro pe Iwuye Oba Charles kẹta ni London yoo ni lori orile-ede Naijiria?
Ero awọn ọmọ ile Adulawo ṣọtọọtọ lori ayeye igbade Oba Charles keta.
Ojọ kẹfa, oṣu kẹfa, ọdun 2023 ni ayẹyẹ iwuye Oba Charles yii yoo waye nile Gẹẹsi.
Sẹ ẹyin le da Oba Charles mo ti e ba pade re?