BBC Osun Debate 2022: Akin Ogunbiyi ni ìpìlẹ̀ ọ̀tun ni ìpínlẹ̀ Oṣun níló báyìí

Ibẹrẹ ọtun ni mo fẹ́ fun ipinle Osun- Akin Ogunbiyi

BBC Yoruba lo sagbekale eto ipade itagbangba ni ipinle Osun.

Ninu eto yii ni awon oludije ti ni oore ọfẹ lati wa sọ ohun ti wọn ni lọkan lati se fun awọn oludibo ati olugbe ni ipinle Osun.

Ogbeni Akin Ogunbiyi to n dije dupo gomina Osun labe asia ẹgbe oṣelu Accord Party naa salaye erongba rẹ fun awọn ara ilu.

Akinibiyi so nipa ipinnu re lori eto aabo, eto ọrọ aje ati ipese iṣẹ.

O tun sọ ohun tuntun to ni fun eto ẹkọ.