You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Coronavirus: Ǹjẹ́ fífi omi àti iyọ̀ yọnu leè dènà àrùn Coronavirus?
Arun Coronavirus ko mọ ọmọde, bẹ ni ko mọ agbalagba, bo ṣe n pa olowo lo n kọlu ẹni ti ko ni.
Ṣugbọn, ṣe fifi omi ati iyọ yọnu lee dena arun naa?
Ajọ eleto ilera lagbaye, WHO ti sọrọ nipa igbagbọ awọn eeyan kan nipa lilo omi ati iyọ lati dena arun ọhun.
BBC Yoruba tu pẹrẹpẹrẹ bo ṣe jẹ.