You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
BBC Gov Debates: Wòlìí Arole polongo ìpàdé ìfọ̀rọ̀wérọ̀ BBC Yorùbá
Awọn ara ipinlẹ Ọyọ ti n reti ilana ti awọn oludije gomina ni ipinlẹ Ọyọ ni lati sọ níbi ipade ifọrọwerọ pẹlu BBC Yoruba.
Deedee agogo mẹsan owurọ ni yoo waye ni gbọngan Professor Ogunlesi ni ilu Ibadan.