You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Mamora sọ wipe owo ti awọn sẹnetọ n gba ti pọju
Sẹnetọ Mamora wipe o yẹ ki wọn se ayẹwo owo ti awọn to n se ijọba n gba latori awn sẹnatọ titi to fi de ori awọn adajọ.