You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Ijọba ipinlẹ Eko ti gbogbo isọ ati ile-isẹ to wa ni Olusosun pa
Awọn onisẹ ọwọ to wa ni agbegbe Olusosun ti ke gbajare wipe ijọba ipinlẹ Eko fẹ gba ounjẹ lẹnu wọn,